Thursday, May 9, 2024
MARKET UPDATE
Advertisement Topt

TheCable

Tag "Ifiidiododomulẹ"

Ọ̀rọ̀ tí wọ́n ní George Weah sọ nípa ifipagba ìjọba ní orílẹ̀-èdè Nije kìí ṣe òótọ́

    Ọ̀rọ̀ tí wọ́n ní George Weah sọ nípa ifipagba ìjọba ní orílẹ̀-èdè Nije kìí ṣe òótọ́

Ọ̀rọ̀ kan tí wọ́n ní George Weah, Ààrẹ orílẹ̀-èdè Liberia sọ ni àwọn ènìyàn ti se atunpin rẹ̀ lórí ohun ìgbàlódé ibaraẹnise. Lára àwọn atẹsita náà lórí ohun ibaraẹnise ẹlẹyẹ

0 comment Read Full Article

Fídíò tí àwọn ènìyàn ṣe atunpin rẹ̀ tí ó ní àwòrán ohun ìjagun kìí se ti orílẹ̀-èdè Nije

    Fídíò tí àwọn ènìyàn ṣe atunpin rẹ̀ tí ó ní àwòrán ohun ìjagun kìí se ti orílẹ̀-èdè Nije

Fídíò kan tí àwọn ènìyàn ń pín kiri tí ó ní àwọn òṣìṣẹ́ ológun níbi tí wọ́n ti ń ṣe karími nínú aṣọ ogun àti ibi tí wọ́n ti ń

0 comment Read Full Article

Ṣé owó pẹtiroolu lítà kan ní Nàìjíríà ló kéré jù l’agbaye bí Ẹniọlá Badmus ṣe wí?

    Ṣé owó pẹtiroolu lítà kan ní Nàìjíríà ló kéré jù l’agbaye bí Ẹniọlá Badmus ṣe wí?

Ẹniọlá Badmus, òṣèré gbajúmọ̀ ti sọ pé biotilẹjẹpe ìjọba Nàìjíríà ti yọ owó kiaramabani àwọn ènìyàn fún epo pẹtiroolu tí ó sì jẹ́ kí owó lítà epo kan lé ju

0 comment Read Full Article

Ṣé Bill Gates ló fa aarun tó ń fa ọgbẹ́ ahọ́n àti ọ̀fun ní Nàìjíríà?

    Ṣé Bill Gates ló fa aarun tó ń fa ọgbẹ́ ahọ́n àti ọ̀fun ní Nàìjíríà?

Ikilọ: Ìròyìn yìí ní àwọn àwòrán tí wọ́n lè kọni lominu. Tí ó bá jẹ́ ọmọ Nàìjíríà tí ó sì máa ń gbọ́ ìròyìn déédéé, ó ṣeéṣe kí ó ti

0 comment Read Full Article

Ṣé Buhari yọ owó kiaramabani àwọn ènìyàn fún díṣù gẹ́gẹ́bí Garba Shehu ṣe wí?

  Ṣé Buhari yọ owó kiaramabani àwọn ènìyàn fún díṣù gẹ́gẹ́bí Garba Shehu ṣe wí?

Ní ọjọ́ Ajé, Garba Shehu, ẹni tí ó jẹ agbẹnusọ fún Ààrẹ Muhammadu Buhari, Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà tẹ́lẹ̀rí sọ wí

0 comment Read Full Article
error: Content is protected from copying.